[Audio & Lyrics] Adeniyi Ogotuntun – Olorun Agbaye
Adeniyi Ogotuntun – Olorun Agbaye
Olorun Agbaye is an inspirational song that cry out God’s mercy over the needs of the people in the world and also to remind God of his blessings to us his children.
The song is a slow tempo song which leaves listeners dancing to the great God concerning the situations on Earth.
Check out Lyrics below
Olorun Agbaye Iwo lanwo bojuwole lat’oke ko Sanu fun wa
Olorun Agbaye Iwo lanwo bojuwole lat’oke ko Sanu fun wa
Sanu fun wa ko ranwalowo o bojuwole lat’oke ko Sanu fun wa
Sanu fun wa ko ranwalowo o bojuwole lat’oke ko Sanu fun wa
*Back to chorus* (Olorun Agbaye(2xc)
lead:Baba boju Anu wo wa lat’oke
Oruko re ni igbala ti awa Fe latimo
Omode nke agbalagba won ke si o bojuwole lat’oke ko Sanu fun wa
*Back to chorus* :Olorun Agbaye
Lead:Alanu ni e tete wa mu leri she,Nigeria orile ede wa do’wo re Olowo nke talaka won ke si o bojuwole lat’oke wa Sanu fun wa
*Back to chorus*:Olorun Agbaye
Awa k’oni eni ti a le sawaba
Iwo l’odi ati asa wa maje k’aiye gan Oro re larawa bojuwole lat’oke ko Sanu fun wa
Back to chorus:Olorun agbaiye
Lead:Sanu fun wa ko ranwalowo o
All:Bojuwole lat’oke ko Sanu fun wa
Lead:Iwo ni balogun orun wa gbewanija(olugbeja sa ni o)
All:bojuwole lat’oke ko Sanu fun wa
Lead:Sanu fun wa Anu re lanbebe fun oo
All:Bojuwole lat’oke ko Sanu fun wa
Lead:Wa nu omije wa nu o wa só ekun wa derin baba
All:Bojuwole lat’oke ko Sanu fun wa.
Listen & Download Below
[audiomack background=”1″ src=”https://audiomack.com/embed/song/ogunloyeadeniyi111/olorun-agbaye-adeniyi-ogotuntun”]